Sáàmù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ni ìpín mi, apá tí ó kàn mí+ àti ife mi.+ O dáàbò bo ogún mi.