Sáàmù 119:147 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 147 Mo ti jí kí ilẹ̀ tó mọ́,* kí n lè kígbe fún ìrànlọ́wọ́,+Nítorí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ ni ìrètí mi.*