Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Hébérù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+
11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.