Sáàmù 69:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó ti rẹ̀ mí nítorí igbe tí mò ń ké;+Ọ̀fun mi ti há. Ojú mi ti di bàìbàì bí mo ṣe ń dúró de Ọlọ́run mi.+
3 Ó ti rẹ̀ mí nítorí igbe tí mò ń ké;+Ọ̀fun mi ti há. Ojú mi ti di bàìbàì bí mo ṣe ń dúró de Ọlọ́run mi.+