Sáàmù 119:82 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 82 Ojú mi fẹ́ máa rí ọ̀rọ̀ rẹ+Nígbà tí mo béèrè pé: “Ìgbà wo lo máa tù mí nínú?”+ Sáàmù 119:123 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 123 Ojú mi ti di bàìbàì bí mo ṣe ń dúró de ìgbàlà rẹ+Àti ìlérí* òdodo rẹ.+ Àìsáyà 38:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mò ń ké ṣíoṣío bí ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà;*+Mò ń ké kúùkúù bí àdàbà.+ Ojú mi ń wo ibi gíga títí ó fi rẹ̀ mí:+ ‘Jèhófà, ìdààmú ti bò mí mọ́lẹ̀;Ràn mí lọ́wọ́!’*+
14 Mò ń ké ṣíoṣío bí ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà;*+Mò ń ké kúùkúù bí àdàbà.+ Ojú mi ń wo ibi gíga títí ó fi rẹ̀ mí:+ ‘Jèhófà, ìdààmú ti bò mí mọ́lẹ̀;Ràn mí lọ́wọ́!’*+