Sáàmù 69:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó ti rẹ̀ mí nítorí igbe tí mò ń ké;+Ọ̀fun mi ti há. Ojú mi ti di bàìbàì bí mo ṣe ń dúró de Ọlọ́run mi.+ Sáàmù 143:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jọ̀ọ́ Jèhófà, tètè dá mi lóhùn;+Agbára* mi ti tán.+ Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi,+Kí n má bàa dà bí àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*+
3 Ó ti rẹ̀ mí nítorí igbe tí mò ń ké;+Ọ̀fun mi ti há. Ojú mi ti di bàìbàì bí mo ṣe ń dúró de Ọlọ́run mi.+
7 Jọ̀ọ́ Jèhófà, tètè dá mi lóhùn;+Agbára* mi ti tán.+ Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi,+Kí n má bàa dà bí àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*+