Òwe 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí àṣẹ jẹ́ fìtílà,+Òfin jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+Àwọn ẹ̀kọ́ inú ìbáwí sì ni ọ̀nà ìyè.+ Mátíù 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ ó dáhùn pé: “A ti kọ ọ́ pé: ‘Kì í ṣe oúnjẹ nìkan ṣoṣo ló ń mú kí èèyàn wà láàyè, àmọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń ti ẹnu Jèhófà* jáde ni èèyàn fi ń wà láàyè.’”+
4 Àmọ́ ó dáhùn pé: “A ti kọ ọ́ pé: ‘Kì í ṣe oúnjẹ nìkan ṣoṣo ló ń mú kí èèyàn wà láàyè, àmọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń ti ẹnu Jèhófà* jáde ni èèyàn fi ń wà láàyè.’”+