Sáàmù 86:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ṣọ́ ẹ̀mí* mi, torí pé adúróṣinṣin+ ni mí. Gba ìránṣẹ́ rẹ tó gbẹ́kẹ̀ lé ọ là,Nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mi.+ Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
2 Ṣọ́ ẹ̀mí* mi, torí pé adúróṣinṣin+ ni mí. Gba ìránṣẹ́ rẹ tó gbẹ́kẹ̀ lé ọ là,Nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mi.+
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’