Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+ Sáàmù 19:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n yẹ ní fífẹ́ ju wúrà,Ju ọ̀pọ̀ wúrà tó dáa,*+Wọ́n sì dùn ju oyin lọ,+ oyin inú afárá. Òwe 24:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọmọ mi, jẹ oyin, nítorí ó dára;Oyin inú afárá sì ń dùn lẹ́nu. 14 Lọ́nà kan náà, mọ̀ pé ọgbọ́n dára fún ọ.*+ Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dáraÌrètí rẹ kò sì ní pa rẹ́.+
7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+
13 Ọmọ mi, jẹ oyin, nítorí ó dára;Oyin inú afárá sì ń dùn lẹ́nu. 14 Lọ́nà kan náà, mọ̀ pé ọgbọ́n dára fún ọ.*+ Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dáraÌrètí rẹ kò sì ní pa rẹ́.+