Sáàmù 25:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọlọ́run mi, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé;+Má ṣe jẹ́ kí ojú tì mí.+ Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi yọ̀ mí.+ Róòmù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìwé Mímọ́ sọ pé: “Kò sí ẹni tó bá gbé ìgbàgbọ́ rẹ̀ lé e tó máa rí ìjákulẹ̀.”+