-
Ìsíkíẹ́lì 22:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Ọmọ èèyàn, ilé Ísírẹ́lì ti dà bí ìdàrọ́ tí kò wúlò lójú mi. Bàbà, tánganran, irin àti òjé tó wà nínú iná ìléru ni gbogbo wọn. Wọ́n ti di ìdàrọ́ fàdákà.+
-