Sáàmù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+
8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+