Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+ Òwe 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Òwe Sólómọ́nì,+ ọmọ Dáfídì,+ ọba Ísírẹ́lì:+ Òwe 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Láti mú kí àwọn aláìmọ̀kan ní àròjinlẹ̀;+Láti mú kí ọ̀dọ́kùnrin ní ìmọ̀ àti làákàyè.+ 2 Tímótì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àti pé láti kékeré jòjòló + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+
7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+
15 àti pé láti kékeré jòjòló + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+