Àìsáyà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Sọ fún àwọn olódodo pé nǹkan máa lọ dáadáa fún wọn;Wọ́n máa jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.*+ Hébérù 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bákan náà, láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa, torí ẹnikẹ́ni tó bá ń tọ Ọlọ́run wá gbọ́dọ̀ gbà gbọ́ pé ó wà àti pé òun ló ń san èrè fún àwọn tó ń wá a tọkàntọkàn.+
6 Bákan náà, láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa, torí ẹnikẹ́ni tó bá ń tọ Ọlọ́run wá gbọ́dọ̀ gbà gbọ́ pé ó wà àti pé òun ló ń san èrè fún àwọn tó ń wá a tọkàntọkàn.+