Sáàmù 51:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+ Àìsáyà 63:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí Jèhófà ṣe torí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ ká yìn,Torí gbogbo ohun tí Jèhófà ti ṣe fún wa,+Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun rere tó ti ṣe fún ilé Ísírẹ́lì,Nínú àánú rẹ̀ àti ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tó lágbára.
51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+
7 Màá sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí Jèhófà ṣe torí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ ká yìn,Torí gbogbo ohun tí Jèhófà ti ṣe fún wa,+Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun rere tó ti ṣe fún ilé Ísírẹ́lì,Nínú àánú rẹ̀ àti ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tó lágbára.