-
1 Sámúẹ́lì 24:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Kí Jèhófà jẹ́ onídàájọ́, kí ó sì dájọ́ láàárín èmi àti ìwọ. Yóò rí i, yóò gba ẹjọ́ mi rò,+ yóò dá ẹjọ́ mi, yóò sì gbà mí lọ́wọ́ rẹ.”
-
-
Sáàmù 43:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Gbà mí lọ́wọ́ ẹlẹ́tàn àti aláìṣòdodo.
-