1 Kíróníkà 22:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kìkì pé kí Jèhófà fún ọ ní làákàyè àti òye+ nígbà tó bá fún ọ ní àṣẹ lórí Ísírẹ́lì, kí o lè máa pa òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́.+ Òwe 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bákan náà, tí o bá ké pe òye+Tí o sì nahùn pe ìfòyemọ̀;+ Òwe 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà náà, wàá lóye ìbẹ̀rù Jèhófà,+Wàá sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.+
12 Kìkì pé kí Jèhófà fún ọ ní làákàyè àti òye+ nígbà tó bá fún ọ ní àṣẹ lórí Ísírẹ́lì, kí o lè máa pa òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́.+
3 Bákan náà, tí o bá ké pe òye+Tí o sì nahùn pe ìfòyemọ̀;+ Òwe 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà náà, wàá lóye ìbẹ̀rù Jèhófà,+Wàá sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.+