ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 30:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Mò ń fi ọ̀run àti ayé ṣe ẹlẹ́rìí lòdì sí ọ lónìí, pé mo ti fi ìyè àti ikú sí iwájú rẹ, ìbùkún àti ègún;+ yan ìyè, kí o lè máa wà láàyè,+ ìwọ àti àwọn àtọmọdọ́mọ+ rẹ,

  • Jóṣúà 24:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àmọ́ tó bá dà bíi pé ó burú lójú yín láti máa sin Jèhófà, ẹ fúnra yín yan ẹni tí ẹ fẹ́ máa sìn lónìí,+ bóyá àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín sìn ní òdìkejì Odò*+ tàbí àwọn ọlọ́run àwọn Ámórì tí ẹ̀ ń gbé ní ilẹ̀ wọn.+ Ṣùgbọ́n ní tèmi àti agbo ilé mi, Jèhófà ni àwa yóò máa sìn.”

  • Jóṣúà 24:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Torí náà, Jóṣúà sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí lòdì sí ara yín pé, ẹ̀yin fúnra yín lẹ pinnu pé Jèhófà lẹ máa sìn.”+ Wọ́n fèsì pé: “Àwa ni ẹlẹ́rìí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́