Sáàmù 25:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ojú mi ń wò nígbà gbogbo,+Nítorí ó máa yọ ẹsẹ̀ mi nínú àwọ̀n.+ Sáàmù 121:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 121 Mo gbé ojú mi sókè sí àwọn òkè.+ Ibo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá?