Sáàmù 141:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ojú rẹ ni mò ń wò, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ.+ Ìwọ ni mo fi ṣe ibi ààbò mi. Má ṣe gba ẹ̀mí mi.*