2 Kíróníkà 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọlọ́run wa, ṣé o ò ní dá wọn lẹ́jọ́ ni?+ Nítorí a ò ní agbára kankan níwájú ọ̀pọ̀ èèyàn tó ń bọ̀ wá bá wa yìí; a ò sì mọ ohun tó yẹ ká ṣe,+ àmọ́ ojú rẹ là ń wò.”+ Sáàmù 25:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ojú mi ń wò nígbà gbogbo,+Nítorí ó máa yọ ẹsẹ̀ mi nínú àwọ̀n.+
12 Ọlọ́run wa, ṣé o ò ní dá wọn lẹ́jọ́ ni?+ Nítorí a ò ní agbára kankan níwájú ọ̀pọ̀ èèyàn tó ń bọ̀ wá bá wa yìí; a ò sì mọ ohun tó yẹ ká ṣe,+ àmọ́ ojú rẹ là ń wò.”+