Sáàmù 36:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Máa fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ hàn nìṣó sí àwọn tó mọ̀ ọ́,+Àti òdodo rẹ sí àwọn tí ọkàn wọn dúró ṣinṣin.+ Sáàmù 73:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 73 Ní tòótọ́, Ọlọ́run ṣe rere fún Ísírẹ́lì, fún àwọn tí ọkàn wọn mọ́.+
10 Máa fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ hàn nìṣó sí àwọn tó mọ̀ ọ́,+Àti òdodo rẹ sí àwọn tí ọkàn wọn dúró ṣinṣin.+