Sáàmù 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run ni apata mi,+ Olùgbàlà àwọn tí ọkàn wọn dúró ṣinṣin.+ Sáàmù 97:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìmọ́lẹ̀ ti tàn fún olódodo,+Ayọ̀ sì kún inú àwọn tí ọkàn wọn dúró ṣinṣin.