Òwe 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Máa kíyè sí i ní gbogbo ọ̀nà rẹ,+Á sì mú kí àwọn ọ̀nà rẹ tọ́.+ Òwe 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìbùkún Jèhófà ló ń sọni di ọlọ́rọ̀,+Kì í sì í fi ìrora* kún un. Òwe 16:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Fi gbogbo ohun tí o bá ń ṣe lé Jèhófà lọ́wọ́,*+Ohun tí o fẹ́ ṣe á sì yọrí sí rere.