Àìsáyà 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+ Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+
3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+ Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+