-
Oníwàásù 5:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Oorun ẹni tó ń sìn máa ń dùn, bóyá oúnjẹ díẹ̀ ló jẹ tàbí púpọ̀, àmọ́ ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ tí ọlọ́rọ̀ ní kì í jẹ́ kó rí oorun sùn.