-
Jẹ́nẹ́sísì 33:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àmọ́ Ísọ̀ sáré pàdé rẹ̀, ó gbá a mọ́ra, ó fi ẹnu kò ó lẹ́nu, wọ́n sì bú sẹ́kún. 5 Nígbà tó gbójú sókè, tó sì rí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ náà, ó bi í pé: “Àwọn wo ló wà pẹ̀lú rẹ yìí?” Ó fèsì pé: “Àwọn ọmọ tí Ọlọ́run fi bù kún ìránṣẹ́+ rẹ ni.”
-