Sáàmù 112:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+ Hébérù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.
112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+
7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.