-
1 Sámúẹ́lì 18:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún Dáfídì, Dáfídì sọ pé: “Ṣé nǹkan kékeré ni lójú yín láti bá ọba dána, nígbà tí mo jẹ́ ọkùnrin aláìní àti ẹni tí a kò fi bẹ́ẹ̀ kà sí?”+
-