Sáàmù 43:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+ Kí wọ́n máa darí mi;+Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+
3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+ Kí wọ́n máa darí mi;+Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+