Ìfihàn 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, ohùn kan dún láti ibi ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Ẹ máa yin Ọlọ́run wa, gbogbo ẹ̀yin ẹrú rẹ̀,+ tó bẹ̀rù rẹ̀, ẹ̀yin ẹni kékeré àti ẹni ńlá.”+
5 Bákan náà, ohùn kan dún láti ibi ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Ẹ máa yin Ọlọ́run wa, gbogbo ẹ̀yin ẹrú rẹ̀,+ tó bẹ̀rù rẹ̀, ẹ̀yin ẹni kékeré àti ẹni ńlá.”+