Sáàmù 134:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 134 Ẹ yin Jèhófà,Gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ Jèhófà,+Ẹ̀yin tó ń ṣiṣẹ́ nínú ilé Jèhófà ní òròòru.+ Sáàmù 135:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 135 Ẹ yin Jáà!* Ẹ yin orúkọ Jèhófà;Ẹ mú ìyìn wá, ẹ̀yin ìránṣẹ́ Jèhófà,+