-
1 Kíróníkà 9:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Àwọn yìí ni àwọn akọrin, àwọn olórí agbo ilé àwọn ọmọ Léfì nínú àwọn yàrá,* àwọn tí a kò yan iṣẹ́ míì fún; nítorí pé ojúṣe wọn ni láti máa wà lẹ́nu iṣẹ́ tọ̀sántòru.
-
-
1 Kíróníkà 23:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Gẹ́gẹ́ bí ohun tí Dáfídì sọ kẹ́yìn pé kí wọ́n ṣe, wọ́n ka iye àwọn ọmọ Léfì láti ẹni ogún (20) ọdún sókè.
-
-
Lúùkù 2:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 ó ti di opó, ó sì ti di ẹni ọdún mẹ́rìnlélọ́gọ́rin (84) báyìí. Kì í pa wíwá sí tẹ́ńpìlì jẹ, ó máa ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ tọ̀sántòru, ó máa ń gbààwẹ̀, ó sì máa ń rawọ́ ẹ̀bẹ̀.
-