Sáàmù 96:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá sínú àwọn àgbàlá rẹ̀. Sáàmù 116:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nínú àwọn àgbàlá ilé Jèhófà,+Láàárín rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù. Ẹ yin Jáà!*+