Sáàmù 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wàá pa àwọn tó ń parọ́ run.+ Jèhófà kórìíra àwọn tó ń hu ìwà ipá àti ìwà ẹ̀tàn.*+