-
Sáàmù 64:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Dáàbò bò mí lọ́wọ́ ohun tí àwọn ẹni ibi ń gbèrò ní ìkọ̀kọ̀,+
Lọ́wọ́ àwùjọ àwọn aṣebi.
-
-
Sáàmù 64:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Wọ́n ń wá ọ̀nà tuntun láti ṣe ohun tí kò tọ́;
Wọ́n ń hùmọ̀ ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí wọn ní ìkọ̀kọ̀;+
Inú kálukú wọn jìn.
-