Sáàmù 140:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn agbéraga dẹ pańpẹ́ pa mọ́ dè mí;Wọ́n fi okùn ta àwọ̀n sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà.+ Wọ́n dẹkùn fún mi.+ (Sélà)
5 Àwọn agbéraga dẹ pańpẹ́ pa mọ́ dè mí;Wọ́n fi okùn ta àwọ̀n sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà.+ Wọ́n dẹkùn fún mi.+ (Sélà)