Róòmù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Sàréè tó ṣí sílẹ̀ ni ọ̀fun wọn, wọ́n ti fi ahọ́n wọn tanni jẹ.”+ “Oró paramọ́lẹ̀* wà lábẹ́ ètè wọn.”+ Jémíìsì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ kò sí èèyàn tó lè kápá ahọ́n. Aláìgbọràn ni, ó sì ń ṣeni léṣe, ó kún fún májèlé tó ń pani.+
13 “Sàréè tó ṣí sílẹ̀ ni ọ̀fun wọn, wọ́n ti fi ahọ́n wọn tanni jẹ.”+ “Oró paramọ́lẹ̀* wà lábẹ́ ètè wọn.”+