-
Sáàmù 36:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Má ṣe jẹ́ kí ẹsẹ̀ àwọn agbéraga tẹ̀ mí mọ́lẹ̀
Tàbí kí ọwọ́ àwọn ẹni burúkú lé mi dà nù.
-
-
Sáàmù 71:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ ẹni burúkú,+
Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tó ń ni èèyàn lára láìtọ́.
-