ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 17:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Dáàbò bò mí bí ọmọlójú rẹ;+

      Fi mí pa mọ́ sábẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.+

       9 Dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú tó ń gbéjà kò mí.

      Lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá alénimádẹ̀yìn* tí wọ́n yí mi ká.+

  • Sáàmù 59:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 59 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi;+

      Dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn tó ń dìde sí mi.+

  • Sáàmù 140:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jèhófà, dáàbò bò mí lọ́wọ́ ẹni burúkú;+

      Máa ṣọ́ mi lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá,

      Àwọn tó ń gbèrò láti mú kí n yọ̀ ṣubú.

  • Mátíù 6:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Má sì mú wa wá sínú ìdẹwò,+ ṣùgbọ́n gbà wá* lọ́wọ́ ẹni burúkú náà.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́