-
1 Sámúẹ́lì 19:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Míkálì sọ Dáfídì kalẹ̀ gba ojú fèrèsé,* kí ó lè sá àsálà.
-
-
Sáàmù 18:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Ó ń gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi tí inú ń bí;
Ìwọ gbé mi lékè àwọn tó ń gbéjà kò mí;+
O gbà mí lọ́wọ́ oníwà ipá.
-
-
Sáàmù 71:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ ẹni burúkú,+
Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tó ń ni èèyàn lára láìtọ́.
-