2 Sámúẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Màá wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ,+ màá sì mú* gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kúrò níwájú rẹ;+ màá jẹ́ kí orúkọ rẹ lókìkí gan-an+ bí orúkọ àwọn ẹni ńlá tó wà láyé. Sáàmù 59:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi;+Dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn tó ń dìde sí mi.+
9 Màá wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ,+ màá sì mú* gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kúrò níwájú rẹ;+ màá jẹ́ kí orúkọ rẹ lókìkí gan-an+ bí orúkọ àwọn ẹni ńlá tó wà láyé.