Sáàmù 146:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà yóò jẹ Ọba títí láé,+Àní Ọlọ́run rẹ, ìwọ Síónì, láti ìran dé ìran. Ẹ yin Jáà!* 1 Tímótì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, kí ọlá àti ògo máa jẹ́ ti Ọba ayérayé,+ ẹni tí kò lè díbàjẹ́,+ tí a kò lè rí,+ Ọlọ́run kan ṣoṣo,+ títí láé àti láéláé. Àmín.
17 Nítorí náà, kí ọlá àti ògo máa jẹ́ ti Ọba ayérayé,+ ẹni tí kò lè díbàjẹ́,+ tí a kò lè rí,+ Ọlọ́run kan ṣoṣo,+ títí láé àti láéláé. Àmín.