Àìsáyà 43:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+ Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+ 1 Kọ́ríńtì 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+
10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+ Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+
4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+