Sáàmù 37:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ 24 Bí onítọ̀hún bá tiẹ̀ ṣubú, kò ní balẹ̀ pátápátá,+Nítorí pé Jèhófà dì í lọ́wọ́ mú.*+ Sáàmù 94:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí mo sọ pé: “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀,”Jèhófà, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ló ń gbé mi ró.+
23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+ 24 Bí onítọ̀hún bá tiẹ̀ ṣubú, kò ní balẹ̀ pátápátá,+Nítorí pé Jèhófà dì í lọ́wọ́ mú.*+