Sáàmù 31:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ adúróṣinṣin sí i!+ Jèhófà ń dáàbò bo àwọn olóòótọ́,+Àmọ́ ó máa ń san èrè tó kún rẹ́rẹ́ fún àwọn tó bá ń gbéra ga.+ Sáàmù 97:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+
23 Ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ adúróṣinṣin sí i!+ Jèhófà ń dáàbò bo àwọn olóòótọ́,+Àmọ́ ó máa ń san èrè tó kún rẹ́rẹ́ fún àwọn tó bá ń gbéra ga.+
10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+