Sáàmù 71:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ìwọ ni ìrètí mi, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ;Ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé* láti ìgbà èwe mi wá.+ Jeremáyà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbùkún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,Ẹni tó fi Jèhófà ṣe ìgbọ́kànlé rẹ̀.+