Àìsáyà 29:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn adití máa gbọ́ ọ̀rọ̀ inú ìwé náà,Àwọn afọ́jú sì máa ríran látinú ìṣúdùdù àti òkùnkùn.+ Àìsáyà 35:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yẹn, ojú àwọn afọ́jú máa là,+Etí àwọn adití sì máa ṣí.+
18 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn adití máa gbọ́ ọ̀rọ̀ inú ìwé náà,Àwọn afọ́jú sì máa ríran látinú ìṣúdùdù àti òkùnkùn.+