-
Àìsáyà 42:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ohun tí màá ṣe fún wọn nìyí, mi ò sì ní fi wọ́n sílẹ̀.”
-
-
Mátíù 9:28-30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Lẹ́yìn tó wọnú ilé, àwọn ọkùnrin afọ́jú náà wá bá a, Jésù sì bi wọ́n pé: “Ṣé ẹ nígbàgbọ́ pé mo lè ṣe é?”+ Wọ́n dá a lóhùn pé: “Bẹ́ẹ̀ ni, Olúwa.” 29 Ó wá fọwọ́ kan ojú wọn,+ ó sọ pé: “Kó rí bẹ́ẹ̀ fún yín gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ yín.” 30 Ojú wọn sì ríran. Lẹ́yìn náà, Jésù kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé: “Kí ẹ rí i pé ẹnì kankan kò mọ ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí.”+
-