Àìsáyà 60:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 60 “Dìde, ìwọ obìnrin,+ tan ìmọ́lẹ̀, torí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé. Ògo Jèhófà ń tàn sára rẹ.+ Àìsáyà 60:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+
20 Oòrùn rẹ ò ní wọ̀ mọ́,Òṣùpá rẹ ò sì ní wọ̀ọ̀kùn,Torí pé Jèhófà máa di ìmọ́lẹ̀ ayérayé fún ọ,+Àwọn ọjọ́ ọ̀fọ̀ rẹ sì máa dópin.+